Exodus 36:16 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n rán marun-un pọ̀ ninu àwọn aṣọ títa náà, lẹ́yìn náà ó rán mẹfa yòókù pọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si so aṣọ-tita marun lù mọ́ ara wọn, ati aṣọ-tita mẹfa lù mọ́ ara wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n so àsọ títa márùn-ún pọ̀ mọ́ ara wọn, wọ́n sì tún so mẹ́fà tó kù mọ́ ara wọn.