Exodus 36:31 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n fi igi akasia ṣe àwọn ọ̀pá ìdábùú mẹẹdogun, marun-un fún àwọn àkànpọ̀ igi tí wọ́n wà ní ẹ̀gbẹ́ gúsù,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ṣe ọpá igi ṣittimu; marun fun apáko ìha kan agọ́ na,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n sì tún ṣe ọ̀pá igi kaṣíà: márùn ún fún pakó ní ìhà kọ̀ọ̀kan Àgọ́ náà,