Exodus 36:33 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n fi ọ̀pá ìdábùú kan la àwọn àkànpọ̀ igi náà láàrin, ọ̀pá náà kan igun kinni-keji àgọ́ náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ṣe ọpá ãrin o yọ jade lara apáko wọnni, lati opin ekini dé ekeji.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n sì ṣe ọ̀pá àárin tí yóò fi jáde láti ìkangun dé ìkangun ní àárin àwọn pákó náà.