Exodus 37:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
àwọn òrùka yìí ni wọ́n máa ń ti ọ̀pá bọ̀ láti fi gbé tabili náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Labẹ igbáti na ni oruka wọnni wà, àye fun ọpá lati fi rù tabili na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn òrùka náà wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ etí rẹ̀ láti gbá àwọn òpó náà mu láti máa fi gbé tábìlì náà.