Exodus 37:24 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Odidi talẹnti wúrà marundinlaadọrin ni ó lò lórí ọ̀pá fìtílà yìí ati àwọn ohun èlò tí wọ́n jẹ mọ́ ti ọ̀pá fìtílà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Talenti kan kìki wurà li o fi ṣe e, ati gbogbo ohunèlo rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì se ọ̀pá fìtílà náà àti gbogbo ohun èlò rẹ̀ láti ara talẹ́ńtì kan tí ó jẹ́ kìkì wúrà.