Exodus 37:27 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó da òrùka wúrà meji meji, ó jó wọn mọ́ abẹ́ ìgbátí pẹpẹ náà lẹ́gbẹ̀ẹ́ kinni-keji, òrùka wọnyi ni wọn yóo máa ti ọ̀pá bọ̀ láti fi gbé pẹpẹ náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ṣe oruka wurà meji si i nisalẹ̀ igbáti rẹ̀ na, ni ìha igun rẹ̀ meji, ìha mejeji rẹ̀, lati ṣe àye fun ọpá wọnni lati ma fi rù u.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó se òrùka wúrà méjì sí ìṣàlẹ̀ ìgbátí náà méjì ní ọ̀kánkán ara wọn láti gbá òpó náà mú láti máa fi gbé e.