Exodus 37:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó sì fi wúrà tí wọ́n fi òòlù lù ṣe àwọn Kerubu meji, ó jó wọn mọ́ igun kinni keji ìtẹ́ àánú náà,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ṣe kerubu wurà meji; iṣẹ lilù li o ṣe wọn, ni ìku mejeji itẹ́-ãnu na;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì se kérúbù méjì láti inú òlù wúrà ní òpin ìbòrí náà.