Exodus 37:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kerubu kinni wà ní igun kinni, Kerubu keji sì wà ní igun keji.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kerubu kan ni ìku kini, ati kerubu keji ni ìku keji: lati ara itẹ́-ãnu li o ti ṣe awọn kerubu na ni ìku mejeji rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó se kérúbù kan ni òpin èkínní, ó sì tún ṣe kérúbù kejì sí èkejì; ní òpin méjèèjì ó ṣe ìtẹ́ àánú ìbòrí wọn.