Exodus 38:29 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn idẹ tí wọ́n dájọ jẹ́ aadọrin ìwọ̀n talẹnti ati ẹgbaa ó lé irinwo (2,400) ìwọ̀n ṣekeli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati idẹ ọrẹ na jẹ́ ãdọrin talenti, ati egbejila ṣekeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Idẹ ara ọrẹ náà jẹ́ àádọ́rin tálẹ́ntì àti egbèjìlá sékélì (2,400 shekels).