Exodus 38:30 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Idẹ yìí ni ó lò láti ṣe ìtẹ́lẹ̀ àwọn ìlẹ̀kùn àgọ́ àjọ, ati pẹpẹ onídẹ, ati àwọn idẹ inú rẹ̀ ati gbogbo àwọn ohun èlò ibi pẹpẹ náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On li o si fi ṣe ihò-ìtẹbọ ẹnu-ọ̀na agọ́ ajọ ati pẹpẹ idẹ na, ati àro idẹ sara rẹ̀, ati gbogbo ohun-èlo pẹpẹ na,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó lò ó láti fi ṣe ihò ìtẹ̀bọ̀ fún ẹnu ọ̀nà àgọ́ àjọ, pẹpẹ idẹ náà pẹ̀lú àrò idẹ rẹ̀ àti gbogbo ohun èlò rẹ̀,