Exodus 38:31 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Lára rẹ̀ ni wọ́n ti ṣe ìtẹ́lẹ̀ àwọn òpó àgọ́ náà yípo ati àwọn èèkàn àgọ́ ati àwọn èèkàn àgbàlá inú rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ihò-ìtẹbọ agbalá, na yikà, ati ìho-ìtẹbọ ẹnu-ọ̀na agbalá, ati gbogbo ekàn agọ́ na, ati gbogbo ekàn agbalà na yikà.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
ihò ìtẹ̀bọ̀ fún àyíká àgbàlá náà àti èyí tí ó wà fún ẹnu ọ̀nà àti gbogbo èèkàn àgọ́ náà fún tabánákù àti èyí tí ó wà fún àyíká àgbàlá náà.