Exodus 38:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó fi igi akasia ṣe àwọn ọ̀pá, ó sì yọ́ idẹ bò wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si fi igi ṣittimu ṣe ọpá wọnni, o si fi idẹ bò wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì fi igi kasíà ṣe àwọn òpó náà, ó sì bò wọ́n pẹ̀lú idẹ.