Exodus 39:35 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bẹ́ẹ̀ náà ni àpótí ẹ̀rí pẹlu àwọn òpó rẹ̀ ati ìtẹ́ àánú náà;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Apoti ẹrí nì, ati ọpá rẹ̀ wọnni, ati itẹ́-ãnu nì;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
àpótí ẹ̀rí pẹ̀lú àwọn òpó rẹ̀ àti ìbòrí àánú;