Exodus 39:36 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ati tabili náà, pẹlu gbogbo àwọn ohun èlò rẹ̀ ati burẹdi ìfihàn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Tabili na, ati gbogbo ohunèlo rẹ̀, ati àkara ifihàn;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
tábìlì pẹ̀lú gbogbo ohun èlò rẹ̀ àti àkàrà ìfihàn;