Exodus 39:42 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún Mose, ni àwọn eniyan Israẹli ṣe gbogbo iṣẹ́ náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gẹgẹ bi gbogbo ohun ti OLUWA fi aṣẹ fun Mose, bẹ̃li awọn ọmọ Israeli ṣe gbogbo iṣẹ na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ti ṣe gbogbo iṣẹ́ náà gẹ́gẹ́ bí OLÚWA ti páṣẹ fún Mósè.