Exodus 4:29 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mose ati Aaroni bá lọ sí Ijipti, wọ́n kó gbogbo àgbààgbà àwọn eniyan Israẹli jọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mose ati Aaroni si lọ, nwọn si kó gbogbo àgba awọn ọmọ Israeli jọ:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mósè àti Árónì pe gbogbo àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì jọ.