Exodus 4:30 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Aaroni sọ gbogbo ohun tí OLUWA sọ fún Mose fún wọn, ó sì ṣe àwọn iṣẹ́ ìyanu náà lójú gbogbo àwọn àgbààgbà náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Aaroni si sọ gbogbo ọ̀rọ ti OLUWA ti sọ fun Mose, o si ṣe iṣẹ-àmi na li oju awọn enia na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Árónì sọ ohun gbogbo tí OLÚWA sọ fún Mósè fún wọn