Exodus 40:36 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ninu gbogbo ìrìn àjò wọn, nígbà tí ìkùukùu yìí bá gbéra kúrò lórí àgọ́ náà, àwọn ọmọ Israẹli á gbéra, wọ́n á sì tẹ̀síwájú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati a si fà awọsanma na soke, kuro lori agọ́ na, awọn ọmọ Israeli a ma dide rìn lọ ni ìrin wọn gbogbo:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní gbogbo ìrìnàjò àwọn ọmọ Ísírẹ́lì nígbàkugbà tí a ba ti fa ikuuku àwọ̀ọsánmọ̀ náà sókè kúrò lórí Àgọ́, wọ́n máa ń jáde lọ;