Exodus 40:37 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn bí ìkùukùu yìí kò bá tíì gbéra, àwọn náà kò ní tíì tẹ̀síwájú títí tí yóo fi gbéra.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn bi a kò fà awọsanma na soke, njẹ nwọn kò ni idide rìn titi ọjọ-kọjọ́ ti o ba fà soke.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
ṣùgbọ́n tí àwọ̀ọsánmọ̀ kò bá gòkè wọn kò ní jáde títí di ọjọ́ tí ó bá gòkè.