Exodus 8:32 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn ọkàn Farao tún le, kò sì jẹ́ kí àwọn eniyan náà lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Farao si mu àiya rẹ̀ le nigbayi pẹlu, kò si jẹ ki awọn enia na ki o lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ni àkókò yìí náà, Fáráò sé ọkàn rẹ le kò sì jẹ́ kí àwọn ènìyàn ó lọ.
Recommended Reading