Exodus 9:31 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbogbo ọ̀gbọ̀ ati ọkà Baali tí ó wà lóko ni ó ti bàjẹ́ patapata, nítorí pé ọkà baali ati ọ̀gbọ̀ náà ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí so ni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A si lù ọgbọ́ ati ọkà barle bolẹ; nitori ọkà barle wà ni ipẹ́, ọgbọ́ si rudi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
(Òwú àti ọkà báálì sí bàjẹ́ ni ìwọ̀n ìgbà ti wọn so ṣùgbọ́n ti ọkà-báálì kò lajú ti òwú kò sì là.