Ezekiel 1:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọ̀kọ̀ọ̀kan ninu wọn ní ojú mẹrin mẹrin ati ìyẹ́ mẹrin mẹrin.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Olukuluku si ni oju mẹrin, olukuluku si ni iyẹ mẹrin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
ṣùgbọ́n ẹnìkọ̀ọ̀kan wọn ní ojú mẹ́rin àti ìyẹ́ apá mẹ́rin.