Ezekiel 10:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà, mo wo orí àwọn Kerubu, mo rí kinní kan róbótó róbótó, wọ́n dàbí òkúta safire, ìrísí wọn dàbí ìtẹ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
MO si wò, si kiye si i, ninu ofurufu ti o wà loke lori awọn kerubu, ohun kan hàn li ori wọn bi okuta safire bi irí aworan itẹ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mo sì wò ó, mo rí ohun kan tó dàbí òkúta sáfírè nínú òfuurufú tó wà lókè orí kérúbù, ìrísí ohun yìí sì dàbí ìtẹ́.