Ezekiel 10:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbogbo ara wọn àtẹ̀yìn wọn, àtọwọ́, àtìyẹ́ ati gbogbo ẹ̀gbẹ́ kẹ̀kẹ́ wọn kún fún ojú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati gbogbo ara wọn, ati ẹhìn wọn, ati ọwọ́ wọn ati iyẹ́ wọn, ati awọn kẹkẹ́, kún fun oju yika kiri kẹkẹ́, ti awọn mẹrẹrin ni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo ara wọn àti ẹ̀yìn, ọwọ́ àti ìyẹ́ wọn àwọn kẹ̀kẹ́ mẹ́rẹ̀ẹ̀rin wọn ló ní ojú tó yí wọn ká.