Ezekiel 10:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mo gbọ́ tí wọ́n pe àwọn àgbá náà ní àgbá tí ń sáré yí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Niti awọn kẹkẹ́, a ke si wọn li etí mi wipe, Kẹkẹ́!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mo gbọ́ tí wọ́n pe àwọn kẹ̀kẹ́ yìí ni “kẹ̀kẹ́ ìpòòyì.”