Ezekiel 11:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Ìwọ ọmọ eniyan, gbogbo àwọn tí wọn ń gbé Jerusalẹmu, ń sọ̀rọ̀ nípa àwọn arakunrin wọn, tí ẹ jọ wà ní ìgbèkùn, àní gbogbo ilé Israẹli; wọ́n ń sọ pé, ‘Wọ́n ti lọ jìnnà kúrò lọ́dọ̀ OLUWA, OLUWA sì ti fún wa ní ilẹ̀ yìí gẹ́gẹ́ bí ohun ìní.’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọmọ enia, awọn ará rẹ, ani awọn ará rẹ, awọn ọkunrin ninu ibatan rẹ, ati gbogbo ile Israeli patapata, ni awọn ti awọn ara Jerusalemu ti wi fun pe, Ẹ jina si Oluwa; awa ni a fi ilẹ yi fun ni ini.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ọmọ ènìyàn, àwọn arákùnrin rẹ, àní àwọn ará rẹ, àwọn ọkùnrin nínú ìbátan rẹ, àti gbogbo ilé Ísírẹ́lì pátapáta, ni àwọn ará Jérúsálẹ́mù ti wí fún pé, ‘Ẹ jìnnà sí OLÚWA, àwa ni a fi ilẹ̀ yìí fún yín ní ìní.’