Ezekiel 11:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí wọ́n bá dé ibẹ̀, wọn óo ṣa gbogbo ohun ẹ̀gbin ati ìríra rẹ̀ kúrò ninu rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn o si wá sibẹ, nwọn o si mu gbogbo ohun irira rẹ̀ ati gbogbo ohun ẽri rẹ̀ kuro nibẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Wọn yóò padà síbẹ̀, wọn ó sì mú gbogbo àwòrán ìríra rẹ̀ àti ìbọ̀rìṣà kúrò.