Ezekiel 11:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mo sì sọ gbogbo ohun tí OLUWA fihàn mí fún àwọn tí wọ́n wà ní ìgbèkùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mo si sọ gbogbo ohun ti Oluwa ti fi hàn mi fun awọn ti igbekùn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mo sì sọ gbogbo ohun tí OLÚWA fihàn mí fún àwọn tó wà ní Ìgbèkùn.