Ezekiel 11:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, sọ àsọtẹ́lẹ̀ burúkú nípa wọn, ìwọ ọmọ eniyan, sọ àsọtẹ́lẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina sọtẹlẹ si wọn, Ọmọ enia, sọtẹlẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà sọtẹ́lẹ̀ nípa wọn; ọmọ ènìyàn, sọ tẹ́lẹ̀.”