Ezekiel 14:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn àgbààgbà Israẹli kan tọ̀ mí wá, wọ́n jókòó siwaju mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
AWỌN kan ninu awọn àgba Israeli si wá sọdọ mi, nwọn si joko niwaju mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Díẹ̀ nínú àwọn alàgbà Ísírẹ́lì wá sọ́dọ̀ mi, wọ́n sì jókòó níwájú mi,