Ezekiel 14:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bí mo bá mú kí ogun jà ní ilẹ̀ náà, tí mo sì pa eniyan ati ẹranko run ninu rẹ̀,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Tabi bi mo mu idà wá sori ilẹ na, ti mo si wipe, Idà, la ilẹ na ja; tobẹ̃ ti mo ke enia ati ẹranko kuro ninu rẹ̀:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Tàbí tí mo bá mú idà kọjá láàrin orílẹ̀ èdè náà tí mo wí pé, ‘Ẹ jẹ́ kí idà kọjá láàrin ilẹ̀ náà,’ tí mo sì tú ìbínú gbígbóná lé wọn lórí nípa ìtàjẹ́sílẹ̀, tí mo pa ènìyàn àti ẹranko inú rẹ.