Ezekiel 16:35 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, ìwọ aṣẹ́wó yìí, gbọ́ ohun tí OLUWA wí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina, iwọ panṣaga, gbọ́ ọ̀rọ Oluwa:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“ ‘Nítorí náà, ìwọ alágbèrè, gbọ́ ọ̀rọ̀ OLÚWA!