Ezekiel 17:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà, ó mú ninu èso ilẹ̀ náà, ó gbìn ín sí ilẹ̀ kan tí ó lọ́ràá, ní ẹ̀bá odò. Ó gbìn ín bí wọn tíí gbin igi wilo.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O mu ninu irugbìn ilẹ na pẹlu, o si gbìn i sinu oko daradara kan; o fi si ibi omi nla, o si gbe e kalẹ bi igi willo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“ ‘Ó mú lára irúgbìn ilẹ̀ náà, ó gbìn ín sí ilẹ̀ ọlọ́ràá, lẹ́gbẹ̀ẹ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀ omi, ó gbìn ín bí igi wílóò.