Ezekiel 18:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ṣugbọn tí ó ń jẹ ẹbọ lórí àwọn òkè, tí ó ń bá aya aládùúgbò rẹ̀ lòpọ̀;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ti kò si ṣe ọkan ninu gbogbo iṣẹ wọnni, ṣugbọn ti o tilẹ ti jẹun lori oke, ti o si ba obinrin aladugbo rẹ̀ jẹ,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
(bó tilẹ̀ jẹ́ pé baba rẹ kò se irú rẹ̀): “Ó ń jẹun lojúbọ lórí òkè gíga, o ba ìyàwó aládùúgbò rẹ̀ jẹ́.