Ezekiel 19:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ̀ka rẹ̀ tí ó lágbára ni a fi gbẹ́ ọ̀pá àṣẹ fún àwọn olórí. Ó dàgbà, ó ga fíofío, láàrin àwọn igi igbó. Ó rí i bí ó ti ga, tí ẹ̀ka rẹ̀ sì pọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ni ọpá ti o le fun ọpá-ade awọn ti o jẹ oye; giga rẹ̀ li a gbega lãrin ẹka gigun, o si farahàn ninu giga rẹ̀ pẹlu ọ̀pọlọpọ ẹka rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ẹ̀ka rẹ̀ lágbára tó láti fi ṣe ọ̀pá àṣẹ ìjòyè, ó ga sókè láàrin ewé rẹ̀, gíga rẹ̀ hàn jáde láàrin ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀ka rẹ̀.