Ezekiel 19:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
kí n sọ pé: Abo kinniun pataki ni ìyá rẹ láàrin àwọn kinniun! Ó dùbúlẹ̀ láàrin àwọn ọ̀dọ́ kinniun, ó ń tọ́jú àwọn ọmọ rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Si wipe, Kini iyá rẹ? Abo kiniun: o dubulẹ lãrin kiniun, o bọ́ awọn ọmọ rẹ lãrin ọmọ kiniun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
wí pé: “ ‘Èwo nínú abo kìnnìnu ni ìyá rẹ̀ ní àárin àwọn kìnnìún yóòkù? Ó sùn ní àárin àwọn ọ̀dọ́ kìnnìún ó sì ń tọ́jú àwọn ọmọ rẹ̀.