Ezekiel 19:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó tọ́ ọ̀kan ninu àwọn ọmọ rẹ̀ dàgbà; ó di ọ̀dọ́ kinniun. Ó kọ́ ọ bí wọ́n tí ń ṣe ọdẹ, ó sì ń pa eniyan jẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si tọ́ ọkan ninu ọmọ rẹ̀ dàgba: o di ọmọ kiniun, o si kọ́ ati ṣọdẹ; o pa enia jẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì tọ́ ọ̀kan nínú àwọn ọmọ rẹ̀ dàgbà, ó sì di kìnnìún tó ní agbára, ó kọ́ ọ láti sọdẹ, ó sì ń pa àwọn ènìyàn jẹ.