Ezekiel 19:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn eniyan ayé gbọ́ nípa rẹ̀, wọ́n tàn án sinu kòtò wọn. Wọ́n fi ìwọ̀ kọ́ ọ nímú, wọ́n sì fà á lọ sí ilẹ̀ Ijipti.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn orilẹ-ède pẹlu gburo rẹ̀: a mu u ninu iho wọn, nwọn si fi ẹ̀wọn mu u lọ si ilẹ Egipti.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn orílẹ̀ èdè gbọ́ nípa rẹ̀, wọ́n sì fi ẹ̀wọ̀n mú un nínú ààfin wọn. Wọn fi ẹ̀wọ̀n mu nu lọ sí ilẹ̀ Éjíbítì.