Ezekiel 19:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí abo kinniun náà rí i pé ọwọ́ tẹ ọmọ òun, ati pé igbẹkẹle òun ti dòfo, ó mú òmíràn ninu àwọn ọmọ rẹ̀, ó tọ́ ọ di ọ̀dọ́ kinniun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati o si ri pe on si duro, ti ireti rẹ̀ si sọnu, nigbana ni o mu omiran ninu ọmọ rẹ̀, o si sọ ọ di ọmọ kiniun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“ ‘Nígbà tí abo kìnìún yìí rí pé ìrètí rẹ̀ sì já sí asán, ó mú ọmọ rẹ̀ mìíràn ó sì tún tọ́ ọ dàgbà di kìnnìún tó ní agbára.