Ezekiel 19:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó ń yan kiri láàrin àwọn kinniun; nítorí ó ti di ọ̀dọ́ kinniun tí ó lágbára, ó kọ́ bí wọn tí ń ṣe ọdẹ, ó sì ń pa eniyan jẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On si lọ soke lọ sodo lãrin awọn kiniun, o di ọmọ kiniun, o si kọ́ lati ṣọdẹ, o si pa enia jẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì ń rìn káàkiri láàrin àwọn kìnnìún nítorí pé ó ti lágbára, o kọ ọdẹ ṣíṣe, ó sì pa àwọn ènìyàn.