Ezekiel 19:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó wó ilé ìṣọ́ wọn lulẹ̀; ó sọ ìlú wọn di ahoro. Ẹ̀rù ba gbogbo Ilẹ̀ náà, ati gbogbo àwọn tí ń gbé ibẹ̀, nígbà tí wọ́n gbọ́ bíbú rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On si mọ̀ awọn opo wọn, o si sọ ilu-nla wọn di ahoro; ilẹ na di ahoro, ati ẹkún rẹ̀, pẹlu nipa ariwo kike ramuramu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì wó odi wọn palẹ̀ ó sì sọ àwọ̀n ìlú wọn di ahoro. Ilẹ̀ náà àti àwọn olùgbé ibẹ̀ sì wà ní ìpayà nítorí bíbú ramúramù rẹ̀.