Ezekiel 19:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn orílẹ̀-èdè bá dójú lé e, wọ́n dẹ tàkúté fún un ní gbogbo ọ̀nà, wọ́n da àwọ̀n wọn bò ó, wọ́n sì mú un ninu kòtò tí wọn gbẹ́ fún un.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni awọn orilẹ-ède kó tì i nihà gbogbo lati ìgberiko wá, nwọn si na awọ̀n wọn le e lori: a mu u ninu iho wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni àwọn orílẹ̀ èdè tó yìí ká dìde sí i, wọn ta ẹ̀wọ̀n fún un, wọn sì mú nínú ihò wọn.