Ezekiel 21:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
A ti pọ́n ọn láti fi paniyan; a ti fi epo pa á, kí ó lè máa kọ mànà bíi mànàmáná. Ọ̀rọ̀ yìí kìí ṣe ọ̀rọ̀ àríyá; nítorí àwọn eniyan mi kọ̀, wọn kò náání ìkìlọ̀ ati ìbáwí mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A pọ́n ọ lati pa enia pupọ; a dán a lati ma kọ màna: awa o ha ma ṣe ariyá? ọgọ ọmọ mi, o gàn gbogbo igi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
a ti pọ́n fún pípa, a sì dan an kí ó lè máa kọ bí mọ̀nàmọ́ná! “ ‘Àwa yóò ha si ọ̀pá aládé ọmọ mi Júdà? Idà kẹ́gàn gbogbo ọ̀pá.