Ezekiel 21:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà, a pọ́n idà náà, a sì fi epo pa á, kí á lè fi lé ẹni tí yóo fi paniyan lọ́wọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On si ti fi i le ni lọwọ lati dán, ki a ba le lò o; idà yi li a pọ́n, ti a si dán, lati fi i le ọwọ́ apani.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“ ‘Idà ní a yàn láti pọ́n, kí ó lè ṣe é gbá mú; a pọ́n ọn a sì dan án, ó ṣetán fún ọwọ́ àwọn apani.