Ezekiel 21:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ìwọ ọmọ eniyan, kígbe, kí o sì pohùnréré ẹkún, nítorí àwọn eniyan mi ni a yọ idà sí; ati àwọn olórí ní Israẹli. Gbogbo wọn ni a óo fi idà pa pẹlu àwọn eniyan mi. Nítorí náà káwọ́ lérí kí o sì máa hu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kigbe, ki o si wu, ọmọ enia: nitori yio wá sori awọn enia mi, yio wá sori gbogbo ọmọ-alade Israeli: ìbẹru nla yio wá sori awọn enia mi nitori idà na: nitorina lu itan rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Sunkún síta, kí ó sì pohùnréré ẹ̀kún, ọmọ ènìyàn, nítorí yóò wá sórí àwọn ènìyàn mi; yóò wá sórí gbogbo ọmọ aládé Ísírẹ́lì ìbẹ̀rù ńlá yóò wá sórí àwọn ènìyàn mi nítorí idà náà; nítorí náà lu oókan àyà rẹ.