Ezekiel 21:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mò ń dán àwọn eniyan mi wò, bí wọ́n bá sì kọ̀, tí wọn kò ronupiwada, gbogbo nǹkan wọnyi yóo ṣẹlẹ̀ sí wọn, Èmi OLUWA Ọlọrun ni mo sọ bẹ́ẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe idanwo ni, ki si ni bi idà na gàn ọgọ na? kì yio si mọ́, ni Oluwa Ọlọrun wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“ ‘Ìdánwò yóò dé dandan. Tí ọ̀pá aládé Júdà èyí tí idà kẹ́gàn, kò bá tẹ ṣíwájú mọ́ ńkọ́? Ni OLÚWA àwọn ọmọ-ogun wí.’