Ezekiel 21:31 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
N óo bínú sí ọ lọpọlọpọ, ìrúnú mi yóo jó ọ bí iná, n óo fà ọ́ lé àwọn oníjàgídíjàgan lọ́wọ́, àwọn tí wọ́n mọ̀ bí wọ́n ṣe ń panirun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi o dà ibinujẹ mi le ọ lori, ninu iná irúnu mi li emi o fẹ si ọ, emi o si fi ọ le awọn eniakenia lọwọ, ti nwọn ni ọgbọn lati parun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Níbẹ̀ ni èmi yóò ti ṣe ìdájọ́ yín, èmi yóò sì fi èémí ìbínú gbígbóná mi bá yín jà.