Ezekiel 21:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Ìwọ ọmọ eniyan, sọ àsọtẹ́lẹ̀ pé èmi: OLUWA Ọlọrun ní: Ẹ wo idà, àní idà tí a ti pọ́n, tí a sì ti fi epo pa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọmọ enia, sọtẹlẹ, si wipe, Bayi li Oluwa wi; Wipe, Idà, idà ti a pọ́n, ti a si dán pẹlu:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ọmọ ènìyàn, sọ tẹ́lẹ̀ wí pé, Èyí yìí ní OLÚWA wí: “ ‘Ìdá kan, Ìdá kan, tí a pọ́n tí a sì kùn