Ezekiel 22:31 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà, n óo bínú sí wọn; n óo fi ìrúnú pa wọ́n rẹ́, n óo sì gbẹ̀san ìwà wọn lára wọn. Èmi OLUWA Ọlọrun ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina ni mo ṣe dà ibinu mi si wọn lori; mo ti fi iná ibinu mi run wọn: mo si ti fi ọ̀na wọn gbẹsan lori ara wọn, li Oluwa Ọlọrun wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà ni mo ṣe ma da ìbínú mi sí wọn lórí; máa fí iná ìbínú mi run wọn: mo si ma fi ọ̀nà wọn gbẹ̀san lórí ara wọn, ní OLÚWA Ọlọ́run wí.”