Ezekiel 23:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Ìwọ ọmọ eniyan, àwọn ọmọbinrin meji kan wà, tí wọ́n jẹ́ ọmọ ìyá kan náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọmọ enia, obinrin meji wà, ọmọbinrin iyá kanna:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ọmọ ènìyàn, obìnrin méjì wà, ọmọ ìyá kan náà.